ADSENSE CODE HERE

Waec 2017 Yoruba Obj And Theory Answers – May/June Expo
2a) I)[gh]- konsonati afafasefetepe akanyan, ti a se enu pe
ii ) H) konsonanti afitan-an-nape aikanyan, ti an fimu pe
iii) (K-) konsonanti afafasepe aikanyan, ti a se enu pe
iv) R)- konsonanti aferigipe akanyan, ti a fegbe enu pe
.
2b)
i )Gh- igbin, agbagba, gbe,gbo
ii )H - ehoro, iho, ahon
iii ) K - kakaki, akara, ika
iv ) R - riri, ara, ero, oro
V )
4. i. ORO ORUKO ASEBEERE: Oro oruko asebeere ni maa n fi ropo oro oruka miiran nini gbolohun ibeere apeere: Ewo wlo.
ii. ORO ORUKO ASOYE: Oro oruko asoye maa n see idiwon bi oro-oruko ti o tele we po ti kan-npa ni ki a fi eyan kun awon kan nigba ti awon kan je wofun.
Apeere: opolopo, ogunlogo
iii. ORO - ORUKO AFIHAN: Oro-Oruko afihan ni a maa n seda eyan asafihan lati ara re.
Apeere: Iyen - Iwonyen
Eyi - Iwonyi
iv. ORO-ORUKO IBIKAN: EYi je oro-oruko ti a maa n nlo 'ibo' tabi ibikan se ibeere fun.
Apeere: Ibadan,Oyo,ita abule
v. ORO-ORUKO IGBA: EYi ni oro-oruko ti o maa n toka si igba akoko ti nikan sele. A le fi igba wo se Ibeere fun un.
Wan lo ni ana
O gbera ni aaro
==================
5ai)
Gbolohun alaye
5aii)
Gbolohun ibeere
5aiii)
Gbolohun ase
5aiv)
Gbolohun amo
5av)
Gbolohun alalaye
5bi)
Ti o ba ri tunde,bami pe
5bii)
-
5biii)
Kani mori Tunde ni,mi o ni wa
5biv)
Yala ko losi Ilorin,tabi kowa si Ogbomoso
5bv)
Kaka ki n losi ileewe, ma lo si oko mi

